Everyday, so God... Bacause of you. i dey live, i dey breath, i dey eat so, I wanna have some talk with you
Orun, silekun i wanna have some talk, [with] you o (2xe)
Nitori re mose n lola Nitori re mose n s'oge Nitori re mose n ra moto
Mowole,M'oboluwa mi soro
Nitori re mose wa laye Nitori re mose n woso sara Nitori re moji l'owuro Mow'aye mi lode ye
A o, Aa a o o ibafeledu'a A o, Aa a o o mowole , M'obolowa mi soro
Nitori re mose n gbo iroyin ayo Lais'owo laisi nkankan Iya oni, layoola o B'oluwa tiwi, be naa lori
Jiji moji lowuro Moji si inu ipese re Ayo at'alafia ye ye
O, o o oni pe ki n ma se beru
A o, Aa a o o ibafeledu'a A o, Aa a o o mowole , M'obolowa mi soro
Melo la fe so Melo lo si n bowa Melo la fe so, eh Melo lo si n bowa
Nitori re mose n sa ko, everyday, eh eh Nitori re mojijo lese mi, oh oh oh, oh oh Ninu iponju, Ninu idamu, b'ebi ba n p'ona mawole, maboluwa mi soro
B'emi o le yan Baye ba foju dimi B'emi o le ni Mawole, maboluwa mi soro
A o, Aa a o o ibafeledu'a A o, Aa a o o mowole , M'obolowa mi soro
Ninu iponju, Ninu idamu, b'ebi ba n p'ona mawole, maboluwa mi soro Mioni foju sunkun mo o Aye loja, oh oh...Orun..Orunile And thats fine by me....eh eh... Oh..ye ye...bring it down...oh oh..Teksty umieszczone na naszej stronie są własnością wytwórni, wykonawców, osób mających do nich prawa.